Blue Divider

International Recruitment Hub

In collaboration with the Shiva Foundation

Language options:

English HINDI Yoruba

Applying for a job in the UK Adult Care Sector

The GLAA is a UK government agency. Our mission is to stop worker exploitation. We have helped workers in the care sector who have been exploited at work to make sure they receive the pay and conditions they are entitled to.…

Read Article

Ìlóye iye owó gbígbé ní UK: Ìtọsọnà fún Àwọn òṣìṣẹ Ìtọjú (Yoruba)

Gẹ́gẹ́ bí Talent.com [2024], àpapọ̀ owó oṣù òṣìṣẹ́ ìtọ́jú UK jẹ́ £23,510 lọ́dún kan. Lẹhin awọn iyọkuro (fun owo-ori ati NI) o le ní £1,685.67 fun oṣu kan ti £389 fun ọsẹ kan. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé èyí lè dàbí owó tí ó pọ̀, ó ṣe pàtàkì láti mọ̀ pé ìnáwó ìgbésí ayé ní …

Read Article

Ìwé Ìsanwó Kan Tí Wọ́n Ṣẹ̀dá (Yoruba)

Agbanisíṣẹ́ rẹ gbọ́dọ̀ pèsè ìwé ìsanwó fún ọ, wọn yóò fún ọ ní ìwé ìsanwó tí a tẹ̀ jáde tàbí kí wọ́n fi ẹ̀yà ẹ̀rọ-ayárabíàsá ránṣẹ́ sí ọ. Àwọn ìwé ìsanwó ni a gbọdọ pèsè lọjọ tàbí ṣáájú Ìsawó fún ọ.…

Read Article

Awọn iwe aṣẹ ti ara ẹni (Yoruba)

Ní orílẹ̀-èdè United Kingdom, gẹ́gẹ́ bíi ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè, àwọn àkọsílẹ̀ ara ẹni kó ipa pàtàkì nínú ìlànà ìgbanisíṣẹ́. Nísàlẹ ni díẹ nínu àwọn Ìwé ti ara ẹni tí o lè nílò nígbà ti o ba n lọ sí èka Ìtọjú: …

Read Article

Adehun rẹ ati Awọn ofin ati Awọn ipo Iṣẹ (Yoruba)

Àdéhùn ìgbanisíṣẹ́ jẹ́ àdéhùn òfin láàárín agbanisíṣẹ́ àti òṣìṣẹ́. Ó gbọ́dọ̀ ṣètò àwọn òfin àti ipò ìgbanisíṣẹ́ rẹ, fún àpẹẹrẹ àkọlé iṣẹ́ rẹ, owó oṣù, wákàtí iṣẹ́, iye tí wọ́n máa san fún ọ, àwọn ojúṣe, ẹ̀tọ́ ìsinmi ọdọọdún, àti bóyá o wà ní àkókò àyẹwò. Awọn wọnyi hàn kedere, àdéhùn kedere tí àwọn méjèèjì, …

Read Article

Ìbùgbé àti Ìgbòkegbodò tí ó yẹ (Yoruba)

Gẹ́gẹ́ bí olùtọ́jú, ó ṣe pàtàkì láti mọ̀ nípa ewu tí ó ní í ṣe pẹ̀lú ibùgbé àti ìrìnnà, pàápàá jùlọ ní ìbámu pẹ̀lú ẹrú ìgbàlódé, ìta-ènìyàn àti ìlòkulò. A ṣe àgbékalẹ Ìwé yìÍ láti ṣe Ìrànlọwọ fún ọ láti mọ àwọn àmì ti Ìbùgbé tí kò yẹ àti tí ó yẹ àti Ìrìnnà ti …

Read Article

Àwọn àmì ti àwọn iṣé Ìgbanisíṣẹ tí kò tọ (Yoruba)

Gẹ́gẹ́ bí òṣìṣẹ́ ìtọ́jú, ó ṣe pàtàkì láti mọ̀ nípa ewu tí ó ní í ṣe pẹ̀lú àwọn ìlànà ìgbanisíṣẹ́, pàápàá jùlọ àwọn tí àwọn àjọ ìgbanisíṣẹ́ ń lò. Àwọn ìlànà ìgbanisíṣẹ́ tí kò tọ́ lè jẹ́ ẹnu-ọ̀nà sí ìlòkulò àti ẹrú ìgbàlódé. …

Read Article

Owó Àìsàn (Yoruba)

Owó Ìyàrá Ìtọjú áÌsàn tí ó bá òfin mu ni iye owó àìsàn tí ó kéré jù tí o gbọ́dọ̀ gbà lọ́wọ́ agbanisíṣẹ́ rẹ bí o bá kúrò níbi iṣẹ́ nítorí àìsàn. Agbanisíṣẹ́ rẹ lè sanwó púpọ̀ lábẹ́ òfin tiwọn, ṣùgbọ́n wọn kò lè san owó tí o dín.…

Read Article

Ìdánilẹkọ ṣáájú Ìgbanisíṣẹ (Yoruba)

Nígbà tí o bá bẹrẹ nínu ojúṣe rẹ tuntun, agbanisíṣẹ rẹ nílò láti fún ọ ni Ìkẹkọọ tí o tọ láti ní ànfààní láti ṣe iṣẹ rẹ. O kó ipa pàtàkì ní Ìpesè díẹ nínu àtìlẹyìn ti ara-ẹni àti àtìlẹyìn ojúlówó fún àwọn ènìyàn tí o ní Ìpèníjà àti ojúse agbanisíṣẹ rẹ ni láti rii …

Read Article

Owó oṣù tó kéré jù lọ ní orílẹ̀-èdè (Yoruba)

Owó oṣù tí ó kéré jù lọ ní orílẹ̀-èdè jẹ́ owó oṣù tó kéré jù ní wákàtí kan ó fẹ́rẹ̀ẹ́ jẹ́ pé gbogbo àwọn òṣìṣẹ́ tọ sí. Kò ṣe bí agbanisíṣẹ́ ṣe kéré tó, wọ́n ṣì ní láti san owó oṣù tó kéré jù. Síbẹ̀síbẹ̀, iye tí o lẹtọ si láti gbà yàtọ̀ ní ìbámu …

Read Article