Yoruba
Èló ni owó Ìlera àti Ìwọlé Ìtọ́jú Àwùjọ (Yoruba)
Nígbà tí o bá béèrè fún Ìwọlé Òṣìṣẹ Ìlera àti Ìtọjú, O nílò láti ní owó tó láti:
San owó Ìforukọsílẹ náà – èyí dá lórí bóyá wà á wà ní UK fún bíi ọdún 3 (£284 fún ẹnìkan) tàbí ju ọdún 3 lọ (£551 fún ẹnìkan). Owó náà jẹ́ kan náà bóyá o forukọsílẹ …
Ẹtọ Ìsinmi Ọdọọdún (Yoruba)
Àwọn òṣìṣẹ́ ìtọ́jú tí wọ́n mọṣẹ́ lórí ìwé ìwọlé ni wọ́n máa ń fún ní ìsinmi ọ̀sẹ̀ tó kéré jù ní lọ́dọọdún, gẹ́gẹ́ bí àwọn òṣìṣẹ́ mìíràn, gẹ́gẹ́ bí òfin ṣe sọ ní pàtó.…





