Yoruba
Ìlà ìrànlọ́wọ́ Ìmúlẹrú ìgbàlódé (Yoruba)
Ìlà ìrànlọ́wọ́ ẹrú ìgbàlódé jẹ́ ohun èlò pàtàkì, tí UK Charity Unseen ń ṣàkóso rẹ̀, láti gbógun ti Ìmúlẹrú ìgbàlódé àti ìlòkulò. Ìlà ìrànlọ́wọ́ náà jẹ́ ohun èlò ńlá, níbi tí àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ ti lè pèsè àlàyé, ìmọ̀ràn àti ìtọ́sọ́nà fún ọ nípa èyíkéyìí ọ̀rọ̀ Ìmúlẹrú ìgbàlódé. …
Àwọn Olórí Ẹgbẹ Àjọ ÌṣèwádìÍ Ìlòkulò Òṣìṣẹ (GLAA) (Yoruba)
Àwọn Olórí Ẹgbẹ Àjọ ÌṣèwádìÍ Ìlòkulò Òṣìṣẹ (GLAA) jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìjọba UK tí ó ní ojúṣe pàtàkì fún ṣíṣe ìlànà àti àwọn ìwé-àṣẹ okòwò tí wọ́n ń pèsè àwọn òṣìṣẹ́ fún àwọn ilé-iṣẹ́ bíi iṣẹ́ ọ̀gbìn, ọgbà, àti ṣíṣe Ìlànà oúnjẹ. …
Ìgbìmọ Àjọ Ìdábòòbò Àgbà Dorset (Yoruba)
Ìgbìmọ̀ Àjọ Ìdábòòbò Àgbà Dorset jẹ́ ẹgbẹ́ àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ àti àjọ tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ papọ̀ pẹ̀lú láti dáàbò bo àwọn àgbàlagbà tí wọ́n wà nínú ewu lọ́wọ́ ìlòkulò, ti ìpalára ńlá tàbí àìfiyèsí.…
Ìgbìmọ Ìtọjú Ìdábòòbò ati Ìkéde Ìwà-Ìbàjẹ Dorset (Yoruba)
Ẹgbẹ́ Ìtọ́jú Dorset ti ṣe àgbékalẹ̀ ààbò lọ́wọ́ Ìdúnkokomọni, Ìkọlù, ìlòkulò, àti àwọn Ọnà mìíràn ti Ìlànà Ìlòkulò Àwùjọ àti Ìlànà Ìkéde Ìwà-Ìbàjẹ. Àwọn ìlànà wọ̀nyí ṣàlàyé ojúṣe nípa ààbò àti ìlànà ìfọwọ́sowọ́pọ̀ nínú àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ níbi tí àwọn àníyàn nípa ààbò, àti àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ mìíràn nípa ìwà àìṣedéédé àti ìwà tí kò tọ́, ti …
Àjọṣepọ Dorset níti Ìlòdìsí-Ìmúlẹrù (Yoruba)
Káàkiri orílẹ̀-èdè náà, oríṣiríṣi àwọn ẹgbẹ́ àwùjọ parapọ ṣọ̀kan láti gbógun ti ẹrú ìgbàlódé àti ìlòkulò. Àjọṣepọ Dorset níti Ìlòdìsí-Ìmúlẹrù bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 2016 ó sì ní èrògbà láti dá ààyè tó lágbára sílẹ̀ fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ káàkiri Dorset lórí àwọn ọ̀rọ̀ nípa ìtajà àti Ìmúlẹrù. …
Bíi o ṣe le ṣe àkíyèsí Ìlòkulò ní àwùjọ tí o gbòòrò (Yoruba)
Ní àwùjọ tí o gbòòrò, àwọn ènìyàn tí wọ́n jẹ́ aláìlera lè jẹ́ àfojúsùn fún àwọn ọ̀nà ìlòkulò mìíràn, gẹ́gẹ́ bíi Ìlo ilé elòmíràn fún jìbìtì àti ìlòkulò ọ̀daràn. …
Awọn apẹẹrẹ ti Jibiti, Ẹtan ati Ifiagbara (Yoruba)
Amy, ọmọ ọdún 25 láti orílẹ̀-èdè South Africa, kósí ẹ̀tàn ìpolówó iṣẹ́ jìbitì nígbà tí ó ń gbìyànjú láti kó lọ sí UK láti wà pẹ̀lú ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀. Ní ìdáhùn sí ìpolówó tí ó ń pèsè àwọn iṣẹ ìtọ́jú ìlera, ó kàn sí ohun tí ó gbàgbọ́ pé ó jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìgbanisíṣẹ́ tó tọ́. …
Apeere ti Ifadowole Gbese (Yoruba)
John, ẹni tí o wá si Britain láti Zimbabwe ní Ìbẹẹrẹ ọdún yìÍ, sọ pé wọn ti fipá mú òun láti yá owó láti ọdọ àwọn mọlẹbí tó iye owó ti £2,000 “owó Ìṣàkóso” fún wíwá iṣẹ rẹ, pẹlú £250 ní oṣù kan tí wọn n yọ kúrò nínu owó oṣù rẹ. Lẹ́yìn ìyálegbe, owó …
Àwọn Ìwádìí nípa Ìmúnisìn Ìgbàlódé ní Ẹ̀ka Ìtọ́jú (Yoruba)
Divya* wá sí UK láti India* láti ṣiṣẹ́ ní ẹ̀ka ìtọ́jú. Wọ́n fi si Ìbùgbé pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ ìtọ́jú mẹ́rin mìíràn. Agbanisíṣẹ́ wọn gba ìwé ìrìnnà wọn wọ́n sì pàṣẹ fún wọn láti buwọ́lu ìwé àdéhùn ọdún mẹ́ta pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ ìtọ́jú náà.…
Àwọn Ìwádìí Ẹjọ́ nípa Ìlòkulò Àwọn Òṣìṣẹ́ ní Ẹ̀ka Ìtọ́jú (Yoruba)
Chloe * kàn sí Ìlà-Ìpè Ìrànwọ ÀÌrí láti sọ pé òun ní láti san owó ìgbanisíṣẹ́ fún àjọ tí ó ju £8,000 lọ. Ní àfikún, ó ní ìyọkúrò láti inú owó oṣù rẹ̀ lóṣooṣù, láìsí àlàyé ìdí tí wọ́n fi ń ṣe wọ́n. Chloe sọ fún ÀÌrí pé òun ń ṣiṣẹ́ fún wákàtí 12 sí …





